ORIKI ILU EKO

Eko Akete Ile Ogbon Eko Aromi sa legbe legbe Eko aro sese maja Eko akete ilu okun alagbalugbu omi, Ta lo ni elomi l'eko? ebiwon pe talo ni abatabutu baba omikomi, talo laabata buutu baba odo kodo Eko adele ti

Continue Reading...

ORIKI OGBOMOSO

Ogbomoso omo ajilete nbi won gbe n jeka ki won oto muko yangan ogbomoso afogbo ja bi esu odara. Ngba ogbomoso ba se o n ti o se tan Bo logbon inu osebi ere ni omo ajileten ba olu ware

Continue Reading...

ORIKI TAPA

ORIKI TAPAỌmọ Olubisi Ọmọ aláro tin jogun ẹsin Ọsọ eyi yẹ Tápà abiru ti ẹmi Ọmọ ajifowurọ dana kulikuli Ẹsọ wẹrẹ ara Ilodo nle Olubisi Àyè Tapa lo wun mi Boba digba oku Tapa mi o ni si nle Wọn

Continue Reading...

ORIKI ILARO

ORIKI ILARO Eji ogogo omo iku lodo toti deri'lewaOmo adiye sun won sebi kuku loku, kiwon to lotatan adiye dide oyan fandaIlaro omo erin lonibu omo efon lo nonaOmo pakan lakan leyin jijo awo ni gbori ile omo ina tin

Continue Reading...

ORIKI IJEBU

Ijebu omo alare, omo awujale, omo arojo joye, omo alagemo ogun woyowoyo, Omo aladiye ogogomoga, omo adiye balokun omilili, ara orokun, ara o radiye, omo ohun seni oyoyonyo, oyoyo mayomo ohun seni olepani, omo dudu ile komobe se njosi, pupa

Continue Reading...

IBADAN

Ibadan mesi Ogo, nile Oluyole. Ilu Ogunmola, olodogbo keri loju ogun. Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya. Ilu Ajayi, o gbori Efon se filafila. Ilu Latosa, Aare-ona kakanfo. Ibadan Omo ajoro sun. Omo a je Igbin yoo,fi ikarahun fo ri mu. Ibadan maja-maja

Continue Reading...

ILE IFE

Ife ooye lagboOmo olodo kan oteereOmo olodo kan otaaraOdo to san wereke,to san werekeTo dehinkunle oshinle to dabataTo dehinkunle adelawe to dokunOnikee ko gbodo bu muAbabaja won ko gbodo BuweOgedegede onisoboro ni yio mu omi do naa gbeSoboro mi wumi,eje

Continue Reading...

EFON ALAYE

EFON ALAAYE1. Efon npele omo olokeOke - ko ma ‘Laye tile ogunEdu Ule Ahun Efon kumoyeLomode lagba lule lokoIbi an bini na seIn mo mo gbagbe UleEfon - Eye o la ke le EfonOlorun laba ri a.Efon npele omo oloke,Edu Ule

Continue Reading...

OSOGBO OROKI

Osogbo oroki asala omo onile obi osogbo ilu aro,omo aro dede bi okun aare o peta arepeta mogba o,osun osogbo pele o,epele o eyin olomoyoyo osgbo oroki gbe onile,otun gbe ajoji osogbo oroki,osogbo oroki omo yeye osun yeye atewogbeja,aniyun labebe oroki

Continue Reading...

Powered by Blogger.